Lirik Lagu Méjì Méjì Brymo

Mò Fí Iyẹ′ Mi Fo
Mò Ri'rè
Mò Wò Waju, Mò W′okéÌrè Dé
Kí ìjò Mọlẹ, Mo Tún Takasúfè

O Dún Mọ Mí òó
O Dún Mọ Mí òó
O Dún Mọ Mí òó òó
O Dún Mọ' Mí òó

Méjì-méjì Làá D'àiyé ò
(Méjì-méjì Làá D′àiyé ò)
Ìfẹ Rẹ Sí Mí, O Jìn Gángan
(Méjì-méjì Làá D′àiyé ò)
Méjì-méjì Làá D'àiyé ò
(Méjì-méjì Làá D′àiyé ò)
Ìfẹ Rẹ Sí Mí, ò Jìn Gángan
(Méjì-méjì Làá D'àiyé ò)

Ọrẹ, Dákun Rò Kò Tó Lọ
Mò Tàràkà, Mo ṣubu
Kín Tó Kọ òun Món Sọ
Yàrá Gbọrọ, Lọrá Fèsì
Ẹsìn O Gbani
Ìwà O Lani
Òún Tó Wùn ′nì Ló Nwa Ní

Ọrẹ, Dákun Rò Kò Tó Lọ
Mo Tàràkà, Mo ṣubu
Kín Tó Mọ òun Món Sọ
Yàrá Gbọrọ, Lọrá Fèsì
Ẹsìn O Gbani
Ìwà O Lani
Òún Tó Wùn'nì Ló Nwa Ni

Mó Fi Iyẹ Mí Fo
Mo Rí′rè
Mó Wò 'wájú, Mo W'òkè
Ìrè Dé
Kí Ijó Mọlẹ, Mo Tún Takasúfè

O Dùn Mọ Mí óò
O Dùn Mọ Mí óò
O Dùn Mọ Mí óò
O Dùn Mọ Mí óò

Méjì-méjì Làá D′àiyé óò
(Méjì-méjì Làá D′àiyé óò)
Ìfẹ Rẹ Sí Mí, O Jin Gángan
(Méjì-méjì Làá D'àiyé óò)
Méjì-méjì Làá D′àiyé óò
(Méjì-méjì Làá D'àiyé óò)
Ìfẹ Rẹ Sí Mí, O Jin Gángan
(Méjì-méjì Làá D′àiyé óò)

Méjì-méjì Làá D'àiyé óò
(Méjì-méjì Làá D′àiyé óò)
Ìfẹ Rẹ Sí Mí O Jin Gángan
(Méjì-méjì Làá D'àiyé óò)
Méjì-méjì Làá D'àiyé óò
(Méjì-méjì Làá D′àiyé óò)
Ìfẹ Rẹ Sí Mí O Jin Gángan
(Méjì Méjì Làá D′àiyé óọ')
 

 
  Brymo   Writed by Admin  6x     2024-12-23 11:48:51

post a comment