Lirik Lagu Àkọ́kọ́ Brymo
Emi Ni, Emi L′eni Na
Okunrin Meta Ati Abo Tan Fi Orin Ko
Emi Ni, Emi L'omo NaOkunrin Merin Ati Abo, Won T′enu Mo
Mo La'nu, Mo Soro
Mo Yo Ake, Mo Foh Oro
Omo Olooforo
Mo Je Akara Oforo
Emi Ni Ah, Emi Ni Oh
Emi Ma L'eni Tan Soh Nigboro
Emi Ni Yaa, Emi Ni Yoo
Awon Mama Gan N′ Soro Ni Popo
Won Lemi L′àkókó
Won Lemi L'àkókó óh-oh
Won Lemi L′àkókó óh-oh
Won Lemi L'àkókó óh-oh
Emi Ni Okunrin Na
T′awon Majesin Nso Pe M'orin Gan
Emi Ni, Emi L′omo Na
Gbogbo Ara Adugbo Lon T'enu Mo
Emi Baba Olowo
Mo Sh'owo, Mo J′ere
Iwa Ati Opolo Lon Lo
Awon Ota Ti Ru Po
Emi Ni Ah, Emi Ni Ah
Emi Ma L′eni Ton Soh Nigboro
Emi Ni Yaa, Emi Ni Yoo
Awon Omoge N' Re′di Ni Popo
Won L'emi L′àkókó
(Iwo L'àkókó)
Won Lemi L′àkókó Oh-oh
(Iwo L'àkókó Oh-oh)
Won Lemi L'àkókó Oh-oh
(Iwo L′àkókó Oh-oh)
Won Lemi L′àkókó Oh-oh
(Iwo L'àkókó Oh-oh)
Won L′emi L'àkókó
(Iwo L′àkókó)
Won Lemi L'àkókó Oh-oh
(Iwo L′àkókó Oh-oh)
Won Lemi L'àkókó Oh-oh
(Iwo L'àkókó Oh-oh)
Won Lemi L′àkókó Oh-oh
(Iwo L′àkókó Oh-oh)
Okunrin Meta Ati Abo Tan Fi Orin Ko
Emi Ni, Emi L'omo NaOkunrin Merin Ati Abo, Won T′enu Mo
Mo La'nu, Mo Soro
Mo Yo Ake, Mo Foh Oro
Omo Olooforo
Mo Je Akara Oforo
Emi Ni Ah, Emi Ni Oh
Emi Ma L'eni Tan Soh Nigboro
Emi Ni Yaa, Emi Ni Yoo
Awon Mama Gan N′ Soro Ni Popo
Won Lemi L′àkókó
Won Lemi L'àkókó óh-oh
Won Lemi L′àkókó óh-oh
Won Lemi L'àkókó óh-oh
Emi Ni Okunrin Na
T′awon Majesin Nso Pe M'orin Gan
Emi Ni, Emi L′omo Na
Gbogbo Ara Adugbo Lon T'enu Mo
Emi Baba Olowo
Mo Sh'owo, Mo J′ere
Iwa Ati Opolo Lon Lo
Awon Ota Ti Ru Po
Emi Ni Ah, Emi Ni Ah
Emi Ma L′eni Ton Soh Nigboro
Emi Ni Yaa, Emi Ni Yoo
Awon Omoge N' Re′di Ni Popo
Won L'emi L′àkókó
(Iwo L'àkókó)
Won Lemi L′àkókó Oh-oh
(Iwo L'àkókó Oh-oh)
Won Lemi L'àkókó Oh-oh
(Iwo L′àkókó Oh-oh)
Won Lemi L′àkókó Oh-oh
(Iwo L'àkókó Oh-oh)
Won L′emi L'àkókó
(Iwo L′àkókó)
Won Lemi L'àkókó Oh-oh
(Iwo L′àkókó Oh-oh)
Won Lemi L'àkókó Oh-oh
(Iwo L'àkókó Oh-oh)
Won Lemi L′àkókó Oh-oh
(Iwo L′àkókó Oh-oh)
post a comment